{"product_id":"9783947184897","title":"E: A Ti Mu","description":"\u003cp\u003eÌwé yìí nṣàlàyé èrò kan tí ó jẹ́ àrà-ọ̀tọ̀ nípa ojú òpó àgbáyé fún fífi dúkìá àfojúrí wé ara wọn (aapu) pẹ̀lú ìṣirò àfojúsùn ọjà títà tí ó jọjú (Biliọnu Dọla), tí a gbé wọ inú sọfwea ti ilé iṣẹ́ dúkìá àfojúrí títí dórí àyẹ̀wò dúkìá àfojúrí (ọjà títà tí ó lè tó Tiriliọnu Dọla).\u003c\/p\u003e\u003cp\u003eÈyí ntúmọ̀ sí pé dúkìá àfojúrí fún gbígbé àti ìdókòwò, bóyá ti àdáni àbí àyálò, ni a lè ṣe alárinà fún ní ọ̀nà tí ó múná dóko tí kò sì fi àkókò ṣòfò. Òun ni ọjọ́ ọ̀la ṣíṣe alárinà dúkìá àfojúrí tí ó jẹ́ ọ̀tun tí ó sì dára fún gbogbo àwọn aṣojú fún dúkìá àfojúrí àti àwọn tí ó ní dúkìá. Ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ pé gbogbo orílẹ̀-edè ni fífi dúkìá àfojúrí wé ara wọn ti ní ìtumọ̀ títí dé orílè-èdè kan sí èkejì.\u003c\/p\u003e\u003cp\u003eDípò “gbígbé” dúkìá wá sí ọ̀dọ̀ olùrà àbí ẹni tí ó fẹ́ yá a lò, níwọ̀n ìgbà tí ojú òpó fífi dúkìá àfojúrí wé ara wọn ti wà, àwọn tí ó ṣeéṣe kí ó jẹ́ olùrà àti olùyálò lè kún ojú òṣùwọ̀n (wá àkọsílẹ̀) kí a sì fi wọ́n wé ara wọn kí a sì fi wọ́n mọ dúkìá tí àwọn aṣojú dúkìá àfojúrí bá gbé jáde.\u003c\/p\u003e\u003cp\u003e\u003c\/p\u003e","brand":"Matthias Fiedler","offers":[{"title":"Default Title","offer_id":47036008825072,"sku":"9783947184897","price":6.99,"currency_code":"USD","in_stock":false}],"thumbnail_url":"\/\/cdn.shopify.com\/s\/files\/1\/0737\/7593\/9824\/files\/9783947184897_p0.jpg?v=1763707681","url":"https:\/\/shop-qa.barnesandnoble.com\/products\/9783947184897","provider":"Barnes \u0026 Noble (DEV)","version":"1.0","type":"link"}